Eko iseda ni ero-ori enia wipe aiye ati gbogbo agbaiye ni Olorun da kuku ju pe lairotele wipe bibe lo-jiji si ni gbogbo nkan fi wa niwiwa.
Awa ngbe oju-aiye kekere ti o dara, ti o da bi keke ofurufu ti o ni ominira fun arare. Lakojopo pelu wiwa laye, isegun ati iku awa nse eleri ewa, oorun didun, ife ati orin.
Gba eyi yewo. Ishiro, imo, igba riru ewe, iwa buburu, iroko, igbeyawo, quasars ati oje-igi; ibi kan ko ni gbogbo won ti wa bi?, nwon wa lojiji bi...?
Ninu gbogbo iran enia ti o ti wa lori ile aiye titi di akoko yi, a ko ni awawi lati ma jewo ti wiwa ni idakejeje ogbon isiro; eni to mu ki gbogbo nkan wa ni isipopada ni ayika wa. O ye ki a wa ni iwa riri laise iyemeji tabi duro bi alaigbagbo.
Fun bi egbedogun odun sehin Dafidi Oba Israeli ko [Iwe Psamlu Orin Dafidi 8:3-4]
"Nigba ti mo ro ộrun rẹ, òṣùpá ati ìràwộ, ti iwọ ti se liana silẹ. Kinni enyan, ti iwọ fi nṣe iranti re?
Ati ọmọ eniyan, ti iwọ fi nbẹ ẹ wo."